Àìsáyà 44:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú èyí tí ó kù ni ó ti ṣe òrìṣà, ère rẹ̀;ó forí balẹ̀ fún un, ó sì sìn ín.Ó gbàdúrà sí i, ó wí pé,“Gbà mí, ìwọ ni Ọlọ́run mi.”

Àìsáyà 44

Àìsáyà 44:16-23