Àìsáyà 38:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa yóò gbà mí làbẹ́ẹ̀ ni àwa yóò sì kọrin pẹ̀lú ohun èlò olókunní gbogbo ọjọ́ ayé wanínú tẹ́ḿpìlì ti Olúwa.

Àìsáyà 38

Àìsáyà 38:19-22