Àìsáyà 38:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Alààyè, àwọn alààyè wọ́n ń yìn ọ́,gẹ́gẹ́ bí èmi ti ń ṣe lónìí;àwọn baba sọ fún àwọn ọmọ wọn nípa òtítọ́ rẹ.

Àìsáyà 38

Àìsáyà 38:15-22