Àìsáyà 36:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èwo nínú àwọn òrìṣà orílẹ̀ èdè wọ̀nyí ló ha ti dáàbò bo ilẹ̀ẹ rẹ̀ kúrò lọ́wọ́ mi? Báwo ni Olúwa ṣe wá le gba Jérúsálẹ́mù kúrò lọ́wọ́ mi?”

Àìsáyà 36

Àìsáyà 36:10-22