Àìsáyà 36:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbo ni àwọn òrìṣà Hámátì àti Ápádì ha wà? Níbo ni àwọn òrìṣà Ṣépáfírámù ha wà? Ǹjẹ́ wọn ti já Ṣamáríà gbà kúrò lọ́wọ́ mi bí?

Àìsáyà 36

Àìsáyà 36:13-22