Àìsáyà 34:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ẹran ijùàti àwọn ọ̀wàwà ni yóò pàdé,àti sátírè kan yóò máa kọ sí èkejìí rẹ̀,iwin yóò máa gbé ibẹ̀ pẹ̀lú,yóò sì rí ibi isinmi fún ara rẹ̀.

Àìsáyà 34

Àìsáyà 34:5-17