Àìsáyà 34:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀gún yóò sì hù jádenínú àwọn ààfin rẹ̀ wọ̀nyí,ẹ̀gún ọ̀gán nínú ìlú olódi rẹ̀.Yóò jẹ́ ibùgbé àwọn akátáàti àgbàlá fún àwọn òwìwí.

Àìsáyà 34

Àìsáyà 34:10-17