Àìsáyà 25:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa, ìwọ ni Ọlọ́run un mi;Èmi yóò gbé ọ ga èmi ó sìfi ìyìn fún orúkọọ̀ rẹnítorí nínú òtítọ́ aláìlẹ́gbẹ́o ti ṣe ohun ńlá,àwọn ohun tí o ti gbèròo rẹ̀ lọ́jọ́ pípẹ́.

2. Ìwọ ti sọ ìlú di àkójọ àlàpà,ìlú olódi ti di ààtàn,ìlú olódi fún àwọn àjèjì ni kò sí mọ́;a kì yóò tún un kọ́ mọ́.

Àìsáyà 25