Àìsáyà 24:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ó rẹ òṣùpá sílẹ̀, ojú yóò sì ti òòrùn;nítorí Olúwa àwọn ọmọ-ogun yóò jọbaní orí òkè Ṣíhónì àti ní Jérúsálẹ́mù,àti níwájú àwọn alàgbà rẹ ní ògo.

Àìsáyà 24

Àìsáyà 24:17-23