Àìsáyà 24:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ilé ayé ni a ó sọ di ahoro pátapátaa ó sì jẹ gbogbo rẹ̀ run. Olúwa ni ó ti sọ ọ̀rọ̀ yìí.

Àìsáyà 24

Àìsáyà 24:1-6