Àìsáyà 24:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

bákan náà ni yóò sì rífún àlùfáà àti àwọn ènìyàn,fún ọ̀gá àti ọmọ ọ̀dọ̀,fún ìya-ilé àti ọmọbìnrin,fún olùtà àti olùrà,fún ayáni àti atọrọfún ayánilówó àti onígbésè.

Àìsáyà 24

Àìsáyà 24:1-12