Àìsáyà 2:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa àwọn ọmọ-ogun ní ọjọ́ kan nípamọ́fún gbogbo agbéraga àti ọlọ́kàn gíganítorí gbogbo àwọn tí a gbéga (ni a ó rẹ̀sílẹ̀),

Àìsáyà 2

Àìsáyà 2:8-21