Àìsáyà 2:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojú agbéraga ènìyàn ni a ó rẹ̀ sílẹ̀a ó sì tẹrí ìgbéraga ènìyàn ba, Olúwa nìkan ṣoṣo ni a ó gbéga ní ọjọ́ náà.

Àìsáyà 2

Àìsáyà 2:3-16