Àìsáyà 16:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fi ọ̀dọ́-àgùntàn ṣe ẹ̀bùnránṣẹ́ sí aláṣẹ ilẹ̀ náà,Láti Ṣẹ́là, kọjá ní ihà,lọ sí orí òkè ọ̀dọ́mọbìnrin Ṣíhónì.

Àìsáyà 16

Àìsáyà 16:1-6