Àìsáyà 15:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Omi Dímónì kún fún ẹ̀jẹ̀,ṣíbẹ̀ èmi ó tún mu ohun tí ó jù báyìí lọ wá sórí Dímónì—kìnnìún kan wá ṣórí àwọn ìṣáǹṣá Móábùàti lórí àwọn tí ó tún ṣẹ́kù sórí ilẹ̀ náà.

Àìsáyà 15

Àìsáyà 15:6-9