2 Tẹsalóníkà 3:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí Olúwa máa tọ́ ọkàn yín sọ́nà sí ìfẹ́ Ọlọ́run àti sínú sùúrù Kírísítì.

2 Tẹsalóníkà 3

2 Tẹsalóníkà 3:1-9