2 Tẹsalóníkà 3:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa sì ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Olúwa ní ti ohun tí ẹ ń ṣe, àti pé àwọn nǹkan wọ̀n-ọn-nì tí a pa láṣẹ fún-un yín ni ẹ̀yin ń ṣe.

2 Tẹsalóníkà 3

2 Tẹsalóníkà 3:2-13