2 Tẹsalóníkà 1:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ó fi ìparun àìnípẹ̀kun jẹ wọ́n níyà, a ó sì se wọn mọ̀ kúrò níwájú Olúwa àti inú ògo agbára rẹ̀

2 Tẹsalóníkà 1

2 Tẹsalóníkà 1:1-12