2 Tẹsalóníkà 1:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun yóò fi ìyà jẹ àwọn tí kò mọ Ọlọ́run àti àwọn tí ń ṣe àìgbọ́ràn sí ìyìn rere Jésù Olúwa wa.

2 Tẹsalóníkà 1

2 Tẹsalóníkà 1:2-12