2 Sámúẹ́lì 8:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lọ́wọ́ Síría àti lọ́wọ́ Móábù àti lọ́wọ́ àwọn ọmọ Ámónì, àti lọ́wọ́ àwọn Fílístínì, àti lọ́wọ́ Ámálékì, àti nínú ìkógun Hadadésérì ọmọ Réhóbù ọba Sóbà.

2 Sámúẹ́lì 8

2 Sámúẹ́lì 8:6-18