2 Sámúẹ́lì 8:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì ọba sì fi wọ́n fún Olúwa pẹ̀lú fàdákà, àti wúrà tí ó yà sí mímọ́, èyí tí ó ti gbà lọ́wọ́ àwọn orilẹ̀-èdè tí ó ti ṣẹ́gun.

2 Sámúẹ́lì 8

2 Sámúẹ́lì 8:9-12