2 Sámúẹ́lì 7:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nǹkan kékeré ni èyí sáà jásí lójú rẹ, Olúwa Ọlọ́run; ìwọ sì ti sọ nípa ìdílé ìránṣẹ́ rẹ pẹ̀lú ní ti àkókò tí o jìnnà. Èyí há ṣe ìwà ènìyàn bí, Olúwa Ọlọ́run?

2 Sámúẹ́lì 7

2 Sámúẹ́lì 7:17-25