2 Sámúẹ́lì 7:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì ọba sì wọlé lọ, ó sì dúró níwájú Olúwa, ó sì wí pé:“Olúwa Ọlọ́run, ta ni èmi, àti kí sì ni ìdílé mi, tí ìwọ fi mú mi di ìsinsin yìí?

2 Sámúẹ́lì 7

2 Sámúẹ́lì 7:17-21