2 Sámúẹ́lì 7:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó máa ṣe baba fún un, òun yóò sì máa jẹ́ ọmọ mi. Bí òun bá dẹ́ṣẹ̀, èmi yóò sì fi ọ̀pá ènìyàn nà án, àti ìnà àwọn ọmọ ènìyàn.

2 Sámúẹ́lì 7

2 Sámúẹ́lì 7:6-17