2 Sámúẹ́lì 7:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ó sì kọ́ ilé fún orúkọ mi, èmi yóò sì fi ìdí ìjọba rẹ kalẹ̀ láéláé.

2 Sámúẹ́lì 7

2 Sámúẹ́lì 7:11-22