2 Sámúẹ́lì 5:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì fi òrìṣà wọn sílẹ̀ níbẹ̀, Dáfídì àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì kó wọn.

2 Sámúẹ́lì 5

2 Sámúẹ́lì 5:20-23