2 Sámúẹ́lì 5:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí sì ni orúkọ àwọn tí a bí fún un ní Jérúsálẹ́mù; Ṣamímúà àti Sóbábù, àti Nátanì, àti Sólómónì.

2 Sámúẹ́lì 5

2 Sámúẹ́lì 5:7-24