2 Sámúẹ́lì 5:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì tún mú àwọn àlè àti aya sí i láti Jérúsálẹ́mù wá, lẹ́yìn ìgbà tí ó ti Hébírónì bọ̀: wọ́n sì bí ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin fún Dáfídì.

2 Sámúẹ́lì 5

2 Sámúẹ́lì 5:4-19