2 Sámúẹ́lì 4:11-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Mélòó mélòó ni, nígbà tí àwọn ìká ènìyàn pa olódodo ènìyàn kan ni ilé rẹ̀ lórí ibùsùn rẹ̀—ǹjẹ́ èmi ha sì lè ṣe aláìbéèrè ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ lọ́wọ́ yín bí? Kí èmi sì mú yín kúrò láàyè.”

12. Dáfídì sì fi àṣẹ fún àwọn ọdọ́mọkùnrin rẹ̀, wọ́n sì pa wọ́n, wọ́n sì gé ọwọ́ àti ẹṣẹ̀ wọn, a sì fi wọ́n há lórí igi ní Hébírónì. Ṣùgbọ́n wọ́n mú orí Íṣíbóṣétì, wọ́n sì sin ín ní ibojì Ábínérì ní Hébírónì.

2 Sámúẹ́lì 4