2 Sámúẹ́lì 5:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì sì tọ Dáfídì wá ní Hébírónì, wọ́n sì wí pé, “Wò ó, egungun rẹ àti ẹran ara rẹ ni àwa ń ṣe.

2 Sámúẹ́lì 5

2 Sámúẹ́lì 5:1-9