2 Sámúẹ́lì 3:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábínérì sì bá àwọn àgbà Ísírẹ́lì sọ̀rọ̀ pé, “Ẹ̀yin ti ń ṣe àfẹ́rí Dáfídì ní ìgbà àtijọ́, láti jọba lórí yín.

2 Sámúẹ́lì 3

2 Sámúẹ́lì 3:14-20