2 Sámúẹ́lì 3:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkọ rẹ̀ sì ń bà a lọ, ó ń rìn, ó sì ń sunkún lẹ́yìn rẹ̀ títí ó fi dé Báhúrímù Ábínérì sì wí fún un pé, “Padà sẹ́yìn!” Òun sì padà.

2 Sámúẹ́lì 3

2 Sámúẹ́lì 3:15-17