2 Sámúẹ́lì 24:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóábù sì fi iye tí àwọn ènìyàn náà jásí lé ọba lọ́wọ́: ó sì jẹ́ òjì ọ̀kẹ́ ọkùnrin alágbára ní Ísírẹ́lì, àwọn onídà: àwọn ọkùnrin Júdà sì jẹ́ ọkẹ mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n ènìyàn.

2 Sámúẹ́lì 24

2 Sámúẹ́lì 24:1-16