2 Sámúẹ́lì 24:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì la gbogbo ilẹ̀ náà já, wọ́n sì wá sí Jérúsálẹ́mù ní òpin oṣù kẹsàn-án àti ogúnjọ́.

2 Sámúẹ́lì 24

2 Sámúẹ́lì 24:3-11