2 Sámúẹ́lì 24:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóábù sì wí fún ọba pé, “Kí Olúwa Ọlọ́run rẹ fi kún ìye àwọn ènìyàn náà, ìyekíye kí ó wù kí wọn jẹ́, ní ọrọrún, ojú Olúwa mi ọba yóò sì rí i: ṣùgbọ́n èétiṣe tí Olúwa mi ọba fi fẹ́ nǹkan yìí?”

2 Sámúẹ́lì 24

2 Sámúẹ́lì 24:1-7