2 Sámúẹ́lì 22:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ìwọ ni ìmọ́lẹ̀ mi, Olúwa; Olúwa yóò sì sọ òkùnkùn mi di ìmọ́lẹ̀.

2 Sámúẹ́lì 22

2 Sámúẹ́lì 22:22-30