2 Sámúẹ́lì 22:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ènìyàn tí ó wà nínú ìyà ni ìwọ ó sì gbàlà;ṣùgbọ́n ojú rẹ wà lára àwọn agbéraga, láti rẹ̀ wọ́n sílẹ̀.

2 Sámúẹ́lì 22

2 Sámúẹ́lì 22:21-32