2 Sámúẹ́lì 22:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Fún aláàánú ni ìwọ ó fi ara rẹ̀ hàn ni aláàánú,àti fún ẹni-ìdúró-ṣinṣin ní òdodo ni ìwọ ó fi ara rẹ hàn ní ìdúró-ṣinṣin ní òdodo.

2 Sámúẹ́lì 22

2 Sámúẹ́lì 22:21-36