2 Sámúẹ́lì 22:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì san fún mi gẹ́gẹ́ bí òdodo mi,gẹ́gẹ́ bí ìwà-mímọ́ mi níwájú rẹ̀.

2 Sámúẹ́lì 22

2 Sámúẹ́lì 22:18-34