2 Sámúẹ́lì 20:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ni ọ̀kan nínú àwọn ẹni àlàáfíà àti tòótọ́ ní Ísírẹ́lì: ìwọ ń wá ọ̀nà láti pa ìlú kan run tí ó jẹ́ ìyá ní Ísírẹ́lì: èéṣe tí ìwọ ó fi gbé ìní Olúwa mì.”

2 Sámúẹ́lì 20

2 Sámúẹ́lì 20:10-23