2 Sámúẹ́lì 20:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì sọ̀rọ̀ wí pé, “Wọ́n ti ń wí ṣáájú pé, ‘Níti bíbéèrè, wọn ó béèrè ní Ábélì’ bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì parí ọ̀ràn náà.

2 Sámúẹ́lì 20

2 Sámúẹ́lì 20:9-22