2 Sámúẹ́lì 2:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábínérì ọmọ Nérì pẹ̀lú àwọn ọkùnrin ti Íṣíbóṣetì ọmọkùnrin Ṣọ́ọ̀lù kúrò ní Máhánáímù, wọ́n sì lọ sí Gíbíónì.

2 Sámúẹ́lì 2

2 Sámúẹ́lì 2:2-20