2 Sámúẹ́lì 2:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àkókò tí Dáfídì fi jọba ní Hébúrónì lórí ilé Júdà sì jẹ́ ọdún méje àti oṣù mẹ́fà.

2 Sámúẹ́lì 2

2 Sámúẹ́lì 2:8-17