2 Sámúẹ́lì 17:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúsálómù sì wí pé, “Ǹjẹ́ pe Húṣáì ará Áríkì, àwa ó sì gbọ́ èyí tí ó wà lẹ́nu rẹ̀ pẹ̀lú.”

2 Sámúẹ́lì 17

2 Sámúẹ́lì 17:3-6