2 Sámúẹ́lì 17:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúsálómù sì fi Ámásà ṣe olórí ogun ní ipò Jóábù: Ámásà ẹni tí í ṣe ọmọ ẹnìkan, orúkọ ẹni tí a ń pè ní Itírà, ará Ísírẹ́lì, tí ó wọlé tọ Ábígáílì ọmọbìnrin Náhásì, arabìnrin Sérúíà, ìyá Jóábù.

2 Sámúẹ́lì 17

2 Sámúẹ́lì 17:22-29