2 Sámúẹ́lì 17:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì wá sí Mahánáímù, Ábúsálómù sì gòkè odò Jódánì, òun àti gbogbo àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì pẹ̀lú rẹ̀.

2 Sámúẹ́lì 17

2 Sámúẹ́lì 17:18-29