2 Sámúẹ́lì 17:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhítófélì sì wí fún Ábúsálómù pé, “Èmi ó yan ẹgbàáfà ọkùnrin èmi ó sì dìde, èmi ó sì lépa Dáfídì lóru yìí.

2 Sámúẹ́lì 17

2 Sámúẹ́lì 17:1-3