2 Sámúẹ́lì 16:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìmọ̀ Áhítófélì tí ó máa ń gbà ni ìgbà náà, ó dàbí ẹni pé ènìyàn béèrè nǹkan lọ́wọ́ Ọlọ́run: bẹ́ẹ̀ ni gbogbo ìmọ̀ Áhítófélì fún Dáfídì àti fún Ábúsálómù sì rí.

2 Sámúẹ́lì 16

2 Sámúẹ́lì 16:16-23