2 Sámúẹ́lì 16:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúsálómù àti gbogbo àwọn ènìyàn, àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì sì wá sí Jérúsálẹ́mù, Áhítófélì sì wà pẹ̀lú rẹ̀.

2 Sámúẹ́lì 16

2 Sámúẹ́lì 16:13-23