2 Sámúẹ́lì 16:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba, àti gbogbo àwọn ènìyàn tí ó ń bẹ lọ́dọ̀ rẹ̀ sì dé Jódánì, ó sì rẹ̀ wọ́n, wọ́n sì sinmi níbẹ̀.

2 Sámúẹ́lì 16

2 Sámúẹ́lì 16:10-20